Gospel music minister Orindoyin Christianah makes debut with a brand new single titled “Baba Ese.”
The title of the single “Baba Esé,” is coined from the Yoruba language which literally means thank you, Father.
It is a heartfelt adoration tune to God, in appreciation of his goodness and endless mercy bestowed on us.
Lyrics – Baba Ese By Christianah Orindoyin
[Chorus]
Ose ose o ,fanu re lori mi
ifere dami si o mama se oba iye .
Verse 1 : Mo n lo mo nbo layo arun o se mi sebi mi
anu re lo se yi fun mi o mama se oba iye.
Chorus: Ose ose o ,fanu re lori mi
ifere dami si o mama se oba iye
Verse 2: Eemi leni taye ti gbagbe iwo lo tun wa miri o,
tawa lemi o ba tun yin bi o se wo o oba.
Chorus: Ose ose o ,fanu re lori mi
ifere dami si o mama se oba iye
Verse 3: Egan gbogbo taye fi n pemi to gan oruko re ninu aye mi,
aanu re loyo mi puro ,
won pada dogo o ,
moyege )3x
titi aye.
[Chorus]
Ose ose o ,fanu re lori mi
ifere dami si o mama se oba iye 2x……..
Lead: Ese ee baba moyin o logo oo
Response: Ese ee Baba ese gan.
Lead : Baba ema se oo oloore .
Response: Ese ee Baba ese gan
Lead: Olorun to laye mi,
olorun toni gbami eseun.
Response: Ese ee Baba ese gan.
Lead: Arugbo Ojo ema se ,
baba moyin o logo.
Response: Ese ee Baba ese gan.
Lead: Bi gbogbo irun orimi je ahon ,
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead : Mole rin mole sako ,
ewo mi bimo se nyan.
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead : Ese eee ,Ema se gan oooo.
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead : Titilai )3x
n o yin o o baba gba .
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead : Okuta ti won kosi le lojo si ,
Opada odigun ile.
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead : Orindoyin nyin o o ,
Olorun tewo gbope.
Response : Ese eee Baba ese gan
Lead : Baba ema se o ,oloore .
Response : Ese eee Baba ese gan
Lead : Molerin mole sako ,
mole demo moti ni o.
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead : Baba ema se o ,Oloore .
Response : Ese eee Baba ese gan .
Lead :- Baba momu yin wa, ese …
Response : Ese eee Baba ese gan …
Connect with Orindoyin on social media:
Facebook: Official Orindoyin
Instagram: Official Orindoyin
YouTube: Christianah Orindoyin Tv